[Skip to Content]

IBA Montage

A pe àjọ rẹ lati fi awọn iforukọsilẹ fun Stevie® Awards Fún Àwọn Agbanisiṣẹ́ Tí Ó Fakọyọ ti ọdún 2024 (Stevie Awards for Great Employers) ( ọdun kẹsan) kalẹ̀, ìdálọ́lá tí ó ga ní àgbáyé fún àwọn àṣeyọrí ti ìṣàkóso ènìyàn, ikọ̀, àti akọ́ṣẹ́-mọṣẹ́, àti àwọn nnkan àti iṣẹ́, àti olùpèsè tuntun, tí ó nṣe ìrànlọ́wọ́ láti ṣẹ̀dá àti mímú kí iṣẹ́ lọ geerege ní àwọn ibi gíga.

Tí o bá fẹ́ gba ìwé ìkópa, tí ń sọ nípa àwọn ìtọ́ni tó péye nípa bí o ti le gbáradì kí o sì fa àwọn tí o yàn kalẹ̀, fa àdírẹ́ẹ̀sì í-meèlì rẹ kalẹ̀ níbí a ó sì firánṣẹ́ nípasẹ̀ í-meèlì sí ọ.  A ní òfin ìpamọ́ tí kò gba gbẹ̀rẹ́ a kò sì ní ṣàpínlò àdírẹ́ẹ̀sì í-meèli rẹ pẹ̀lú ẹlòmíràn, fún èyíkéyìí èrèdí.

Èyí ni ojú-ewé kan ṣoṣo lórí ojúlé-wẹ́ẹ̀bù yìí tí wàá rí ní èdè yìí.  Gbogbo ojú-ewé míràn wà ní èdè Gẹ̀ẹ́sì, bí ó ti jẹ́ ìwé ìkópa.  Èyí jẹ́ nítorí a bèrè wípé kí a fa yíyani sílẹ̀ ní èdè Gẹ̀ẹ́sí, kí àwọn gbajúgbajà ìṣòwò káàkiri àgbáyé le kópa nínu ìgbésẹ̀ dídájọ́.  Ìwọ̀nyí ni ìjúwe ránpẹ́ nípa àwọn àmì ẹ̀yẹ náà, àwọn àmúyẹ fún ìfikalẹ̀, àti àwọn ànfààní kíkópa. Tí o bá pinnu pé àjọ rẹ yóò fa àwọn ènìyàn kalẹ̀ fún àwọn àmì ẹ̀yẹ náà, rántí pé o gbọ́dọ̀ ṣètò àwọn ìfàkalẹ̀ rẹ ní Èdè Gẹẹsi.

Nipa Stevie® Awards for Great Employers

Stevie® Awards for Great Employers  nìkan ni ètò àmì ẹ̀yẹ kárí-ayé láti mọ rírì àwọn akọ́ṣẹ́-mọṣẹ́ nípa ìsàkóso ènìyàn àti àwọn agbanisíṣẹ́ tí ó dára jùlọ ní àgbáyé. Ilé-iṣẹ́ Stevie Awards, èyítí ń fúnni ní àmì ẹ̀yẹ náà, wà ní orílẹ̀-èdè United States.   Wọn jẹ awọn oluṣeto ti awọn idije Stevie Awards mẹjọ mẹjọ, lori eyiti o le wa alaye lori www.StevieAwards.com.  Ẹ̀bùn Àmìn Ẹ̀yẹ Stevie Award ti di ọ̀kan nínú àwọn ẹ̀bùn àgbáyé tí ènìyàn le gbà.

Ni ọdun 2023, Awọn ẹbun Stevie fun Awọn agbanisiṣẹ Nla ni a gbekalẹ si awọn ẹgbẹ ati awọn eniyan kọọkan lati awọn orilẹ-ede to ju 28 lọ. Tẹ ibi lati wo àtòkọ awọn to jáwé olúborí ninu abala 2023.

Àwọn ìsọ̀rí

Oríṣi ìsọ̀rí àmì ẹ̀yẹ mẹ́fà ni ó wà láti yàn lára rẹ̀ nínú Stevie® Awards for Great Employers.  Tí o bá yàn láti kópa, wàá yan àwọn ìsọ̀rí tó dọ́gba pẹ̀lú àwọn àṣeyọrí tí o fẹ́ ká fi dá ilé-iṣẹ́ rẹ mọ̀, wàá sì gbáradì fún yíyàn rẹ gẹ́gẹ́ bíi àwọn ìtọ́ni fún àwọn ìsọ̀rí náà.  Láàrín àwọn ìsọ̀rí tó wà nílẹ̀ ni àwọn wọ̀nyí:

Atokọ ati apejuwe ti awọn ẹka ti o rii ninu ohun elo iforukọsilẹ. 

Nínú gbogbo àwọn ìsọ̀rí ìwọ yóò lè yàn láti pèsè àwọn ìdáhùn tí a fi ọwọ́ kọ sí àwọn ìbéèrè náà, tàbí fidio tí ó gùn tó ìṣẹ́jú márún tí ó ndáhùn àwọn ìbéèrè náà.

Àwọn olùbásọ̀rọ̀

Awọn Aṣa Stevie Awards ni awọn aṣoju ni ọpọlọpọ awọn orilẹ-ede. Awọn aṣoju wọnyi yoo kaakiri alaye ati awọn ẹgbẹ iranlọwọ jakejado orilẹ-ede kopa ninu awọn ami-ẹri naa.

Lati pinnu boya aṣoju kan wa ni orilẹ ede rẹ, tẹ ibi.

O tun le kan si awọn oluṣeto ni adirẹsi atẹle:

The Stevie Awards
10560 Main Street, Suite 519
Fairfax, Virginia 22030, USA
Ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀: +1 703-547-8389
Fax: +1 703-991-2397
Àdírẹ́sì email: help@stevieawards.com

Share